Psalms 22:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìwọ ni àwọn baba wa gbẹ́kẹ̀lé; wọ́n gbẹ́kẹ̀lé ọ, o sì gbà wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn baba wa gbẹkẹle ọ: nwọn gbẹkẹle, iwọ si gbà wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn babańlá wa ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú un Rẹ; wọ́n ní ìgbẹ́kẹ̀lé, ìwọ sì gbà wọ́n.