Psalms 24:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ló ni ilẹ̀ ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀, òun ló ni ayé, ati gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
TI Oluwa ni ilẹ, ati ẹkún rẹ̀; aiye, ati awọn ti o tẹdo sinu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ti OLÚWA ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún Rẹ̀, ayé àti àwọn tí ó tẹ̀dó sínú Rẹ̀;