Psalms 24:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ta ni Ọba ògo yìí? OLUWA àwọn ọmọ ogun, òun ni Ọba ògo náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tali Ọba ogo yi? Oluwa awọn ọmọ-ogun; on na li Ọba ogo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ta ni ọba ogo náà? OLÚWA àwọn ọmọ ogun Òun ni ọba ògo náà. Sela