Psalms 25:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Irú ẹni bẹ́ẹ̀ yóo ní ọpọlọpọ ọrọ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ ni yóo sì jogún ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkàn rẹ̀ yio joko ninu ire, irú-ọmọ rẹ̀ yio si jogun aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò lo ọjọ́ wọn nínú àlàáfíà, àwọn ọmọ wọn yóò sì gba ilẹ̀ náà.