Psalms 25:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni OLUWA ń mú ní ọ̀rẹ́, a sì máa fi majẹmu rẹ̀ hàn wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aṣiri Oluwa wà pẹlu awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀, yio si fi wọn mọ̀ majẹmu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA fi ọkàn tán, àwọn tí o bẹ̀rù u Rẹ̀; ó sọ májẹ̀mú Rẹ̀ di mímọ̀ fún wọn.