Psalms 25:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ni mò ń wò lójú nígbà gbogbo, nítorí òun ni yóo yọ ẹsẹ̀ mi kúrò ninu àwọ̀n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju mi gbé soke si Oluwa lai; nitori ti yio fà ẹsẹ mi yọ kuro ninu àwọn na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú mi gbé sókè sọ́dọ̀ OLÚWA, nítorí pé yóò yọ ẹsẹ̀ mi kúrò nínú àwọ̀n náà.