Psalms 25:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mú ìdààmú ọkàn mi kúrò; kí o sì yọ mí ninu gbogbo ìpọ́njú mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iṣẹ́ aiya mi di pupọ: mu mi jade ninu ipọnju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tì mí lẹ́yìn kúrò nínú ìpọ́njú àyà mi; kí o sì fà mí yọ kúrò nínú ìpọ́njú ù mi.