Psalms 25:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wo iye ọ̀tá tí èmi nìkan ní, ati irú ìkórìíra ìkà tí wọ́n kórìíra mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò awọn ọta mi, nwọn sá pọ̀; nwọn si korira mi ni irira ìka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyẹ̀sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀tá mi, tí wọn kórìírá a mi pẹ̀lú ìwà ìkà wọn.