Psalms 25:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Olóore ati olódodo ni OLÚWA, nítorí náà ni ó ṣe ń fi ọ̀nà han àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Rere ati diduro-ṣinṣin ni Oluwa: nitorina ni yio ṣe ma kọ́ ẹlẹṣẹ li ọ̀na na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rere àti ẹni ìdúró ṣinṣin ní OLÚWA: nítorí náà ó kọ́ àwọn ẹlẹ́sẹ̀ ni ọ̀nà náà.