Psalms 27:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn aṣebi bá ń gbógun bọ̀ wá bá mi, tí wọ́n fẹ́ pa mí, àwọn alátakò ati àwọn ọ̀tá mi, wọn óo kọsẹ̀, wọn óo sì ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn enia buburu, ani awọn ọta mi ati awọn abinuku mi sunmọ mi lati jẹ ẹran ara mi, nwọn kọsẹ, nwọn si ṣubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àwọn ènìyàn búburú kọjú ìjà sí mi láti jẹ ẹran ara mi, àní àwọn ọ̀ta mi àti àwọn abínúkú ù mi, wọn yóò kọsẹ̀, wọn yóò sì ṣubú.