Psalms 27:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nisinsinyii n óo ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá mi tí ó yí mi ká; n óo rúbọ ninu àgọ́ rẹ̀ pẹlu ìhó ayọ̀, n óo sì kọ orin aládùn sí OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbayi li ori mi yio gbé soke ga jù awọn ọta mi lọ, ti o yi mi ká, nitorina li emi o ṣe rubọ ayọ̀ ninu agọ rẹ̀; emi o kọrin, nitõtọ emi o kọrin iyìn si Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìsinsin yìí a ti gbé orí mi sókè ga ju ti àwọn ọ̀tá a mi lọ tí ó yí mí ká; èmi yóò rúbọ nínú àgọ́ Rẹ ẹbọ ariwo àti ti ayọ̀; èmi yóò kọrin àní orin dídùn sí OLÚWA.