Psalms 28:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má ṣe kó mi lọ pẹlu àwọn eniyan burúkú, pẹlu àwọn tí ń ṣe iṣẹ́ ibi, àwọn tí ń bá àwọn aládùúgbò wọn sọ ọ̀rọ̀ alaafia, ṣugbọn tí ètekéte ń bẹ ninu ọkàn wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Máṣe fà mi lọ pẹlu awọn enia buburu, ati pẹlu awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ, ti nsọ̀rọ alafia si aladugbo wọn, ṣugbọn ìwa-ìka mbẹ̀ li ọkàn wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú ènìyàn búburú àti, pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, tí ń sọ̀rọ̀ àlàáfíà sí aládùúgbò wọn ṣùgbọ́n tí ìwà ìkà ń bẹ nínú wọn.