Psalms 28:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé wọn kò ka iṣẹ́ OLUWA sí, wọn kò sì bìkítà fún iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀, OLUWA yóo sọ wọ́n di ilẹ̀, kò sì ní gbé wọn dìde mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti nwọn kò kà iṣẹ Oluwa si, tabi iṣẹ ọwọ rẹ̀; on o run wọn, kì yio si gbé wọn ró.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé wọn kò ka iṣẹ́ OLÚWA sí, tàbí àwọn isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ òun ó rún wọn wọlẹ̀ kò sì ní tún wọn kọ́ mọ́.