Psalms 29:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA yóo fún àwọn eniyan rẹ̀ ní agbára; OLUWA yóo fún wọn ní ibukun alaafia.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa yio fi agbara fun awọn enia rẹ̀; Oluwa yio fi alafia busi i fun awọn enia rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí OLÚWA fi agbára fún àwọn ènìyàn Rẹ̀; bùkún àwọn ènìyàn Rẹ̀ pẹ̀lú àlàáfíà.