Psalms 29:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
À ń gbọ́ ohùn OLUWA lójú omi òkun, Ọlọrun ológo ń sán ààrá, Ọlọrun ń sán ààrá lójú alagbalúgbú omi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohùn Oluwa mbẹ lori omi pupọ̀: Ọlọrun ogo nsán ãrá: Oluwa mbẹ lori omi pupọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohùn OLÚWA ré àwọn omi kọjá; Ọlọ́run ògo sán àrá, OLÚWA náà, alágbára ń bẹ lóríi omi púpọ̀.