Psalms 29:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ń mú kí òkè Lẹbanoni ta pọ́núnpọ́nún bí ọmọ mààlúù, ó sì mú kí òkè Sirioni máa fò bí akọ ọmọ mààlúù-igbó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O mu wọn fò pẹlu bi ọmọ-malu; Lebanoni on Sirioni bi ọmọ agbanrere.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó mú Lébánónì fo bí i ọmọ màlúù, àti Síríónì bí ọmọ àgbáǹréré.