Psalms 3:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, àwọn ọ̀tá mi pọ̀ pupọ! Ọ̀pọ̀ ni ó ń dìde sí mi!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA, awọn ti nyọ mi li ẹnu ti npọ̀ to yi! ọ̀pọlọpọ li awọn ti o dide si mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àdúrà Dáfídì Nígbà Tí ó Ṣá Fún Ọmọ Rẹ̀ Ábúsálómù OLÚWA, báwo ni àwọn ọ̀ta mi ṣe pọ̀ tó! Báwo ni àwọn ti ó dìde sí mi ṣe pọ̀ tó!