Psalms 3:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dìde, OLUWA, gbà mí, Ọlọrun mi! Nítorí ìwọ ni o lu gbogbo àwọn ọ̀tá mi bolẹ̀, tí o sì ṣẹgun àwọn eniyan burúkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dide Oluwa; gbà mi, Ọlọrun mi: nitori iwọ li o lù gbogbo awọn ọta mi li egungun ẹrẹkẹ; iwọ si ká ehin awọn enia buburu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dìde, OLÚWA! Gbà mí, Ọlọ́run mi! Lu gbogbo àwọn ọ̀ta mi ní àgbọ̀n; kí o sì ká eyín àwọn ènìyàn búburú.