Psalms 30:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, o ti yọ mí kúrò ninu isà òkú o sọ mí di ààyè láàrin àwọn tí wọ́n ti wọ inú kòtò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, iwọ ti yọ ọkàn mi jade kuro ninu isa-okú: iwọ o si pa mi mọ́ lãye, ki emi ki o má ba lọ sinu iho.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA, ìwọ ti yọ ọkàn mi jáde kúrò nínú isà òkú mú mi padà bọ̀ sípò alààyè kí èmi má baà lọ sínú ihò.