Psalms 31:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé ìbànújẹ́ ni mo fi ń lo ayé mi; ìmí ẹ̀dùn ni mo sì fi ń lo ọdún kan dé ekeji. Ìpọ́njú ti gba agbára mi; gbogbo egungun mi sì ti di hẹ́gẹhẹ̀gẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi fi ibinujẹ lò ọjọ mi, ati ọdun mi ti on ti imi-ẹ̀dun: agbara mi kú nitori ẹ̀ṣẹ mi, awọn egungun mi si run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi fi ìbànújẹ́ lo ọjọ́ mi àti àwọn ọdún mi pẹ̀lú ìmí ẹ̀dùn; agbára mi ti kùnà nítorí òṣì mi, egungun mi sì ti rún dànù.