Psalms 31:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni ẹ̀gàn ni mí láàrin gbogbo àwọn ọ̀tá mi, àwòsọkún ni mí fún àwọn aládùúgbò. Mo di àkòtagìrì fún àwọn ojúlùmọ̀ mi, àwọn tí ó rí mi lóde sì ń sá fún mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi di ẹni-ẹ̀gan lãrin awọn ọta mi gbogbo, pẹlupẹlu lãrin awọn aladugbo mi, mo si di ẹ̀ru fun awọn ojulumọ mi: awọn ti o ri mi lode nyẹra fun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi di ẹni ẹ̀gàn láàrin àwọn ọ̀tá mi gbogbo, pẹ̀lú pẹ̀lú láàrin àwọn aládùúgbò mi, mo sì di ẹ̀rù fún àwọn ojúlùmọ̀ mi; àwọn tí ó rí mi ní òde ń yẹra fún mi.