Psalms 31:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ kí àwọn òpùrọ́ yadi, àní àwọn tí ń fi ìgbéraga ati ẹ̀gàn sọ̀rọ̀ àìdára nípa olódodo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ète eke ni ki a mu dakẹ; ti nsọ̀rọ ohun buburu ni igberaga ati li ẹ̀gan si awọn olododo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí àwọn ètè irọ́ kí ó dákẹ́ jẹ́ẹ́ pẹ̀lú ìgbéraga àti ìkẹ́gàn. wọ́n sọ̀rọ̀ àfojúdi sí olódodo.