Psalms 31:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni ìyìn ni OLUWA, nítorí pé, lọ́nà ìyanu, ó fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn mí, nígbà tí ilẹ̀ ká mi mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olubukún ni Oluwa; nitori ti o ti fi iṣeun-ifẹ iyanu rẹ̀ hàn mi ni ilu olodi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olùbùkún ni OLÚWA, nítorí pé ó ti fi àgbà ìyanu ìfẹ́ tí ó ní sí mi hàn nígbà tí mo wà ní ìlú tí wọ́n rọ̀gbà yí ká.