Psalms 32:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí n kò jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi, ó rẹ̀ mí wá láti inú, nítorí kíkérora tí mò ń kérora ní gbogbo ìgbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati mo dakẹ, egungun mi di gbigbo nitori igbe mi ni gbogbo ọjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí mo dákẹ́, egungun mi di gbígbó dànù nípa ìkérora mi ní gbogbo ọjọ́.