Psalms 33:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA bojúwo ilẹ̀ láti ọ̀run, ó rí gbogbo eniyan;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa wò lati ọrun wá, o ri gbogbo ọmọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA wò láti ọ̀run wá; Ó sì rí gbogbo ìran ènìyàn.