Psalms 33:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti orí ìtẹ́ rẹ̀ tí ó gúnwà sí, ó wo gbogbo aráyé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati ibujoko rẹ̀ o wò gbogbo araiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbi tí ó ti jókòó lóríi ìtẹ́ Ó wo gbogbo àwọn olùgbé ayé