Psalms 33:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òun ni ó dá ọkàn gbogbo wọn, tí ó sì ń mójútó gbogbo ìṣe wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ṣe aiya wọn bakanna; o kiyesi gbogbo iṣẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ẹni tí ó ṣe àyà wọn bákan náà, ó sì kíyèsí ìṣe wọn.