Psalms 33:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kì í ṣe pípọ̀ tí àwọn ọmọ ogun pọ̀ ní ń gba ọba là; kì í sì í ṣe ọ̀pọ̀ agbára níí gba jagunjagun là.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kò si ọba kan ti a ti ọwọ ọ̀pọ ogun gba silẹ: kò si alagbara kan ti a fi agbara pupọ̀ gba silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kò gba ọba kan là nípaṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ ogun; kò sì sí jagunjagun tí a gbà sílẹ̀ nípa agbára ńlá Rẹ̀.