Psalms 33:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ọ̀rọ̀ OLUWA dúró ṣinṣin; òtítọ́ sì ni ó fi ń ṣe gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti ọ̀rọ Oluwa tọ́: ati gbogbo iṣẹ rẹ̀ li a nṣe ninu otitọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé ọ̀rọ̀ OLÚWA dúró ṣinṣin, gbogbo iṣẹ́ Rẹ̀ ni à ń ṣe nínú òtítọ́.