Psalms 35:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo fi gbogbo ara wí pé, “OLUWA, ta ni ó dàbí rẹ? Ìwọ ni ò ń gba aláìlágbára lọ́wọ́ ẹni tí ó lágbára tí o sì ń gba aláìlágbára ati aláìní lọ́wọ́ ẹni tí ó fẹ́ fi wọ́n ṣe ìjẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo egungun mi ni yio wipe, Oluwa, tali o dabi iwọ, ti ngbà talaka lọwọ awọn ti o lagbara jù u lọ, ani talaka ati alaini lọwọ ẹniti nfi ṣe ikogun?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo egúngún mi yóò wí pé, “ìwọ OLÚWA, ta ni ó dà bí i Rẹ̀? O gba talákà là lọ́wọ́ àwọn tí ó lágbára jù wọ́n lọ, talákà àti aláìní lọ́wọ́ ẹni tí ń fi ṣe ìkógun?”