Psalms 35:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn nígbà tí èmi kọsẹ̀, wọ́n kó ara wọn jọ, wọ́n ń yọ̀, wọ́n kó tì mí; pàápàá jùlọ, àwọn àlejò tí n kò mọ̀ rí bẹ̀rẹ̀ sí purọ́ mọ́ mi léraléra.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ninu ipọnju mi nwọn yọ̀, nwọn si kó ara wọn jọ: awọn enia-kenia kó ara wọn jọ si mi, emi kò si mọ̀; nwọn fa mi ya, nwọn kò si dakẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nínú ìkọ̀sẹ̀ mi wọ́n kó ara wọn jọ wọ́n sì yọ̀, wọ́n kó ara wọn jọ sí mi; àní àwọn tí èmi kò mọ̀ wọ́n fà mí ya wọ́n kò sì dákẹ́.