Psalms 35:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí pẹ̀gàn mi, wọ́n ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà; wọ́n sì ń wò mí bíi pé kí n kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlu awọn àgabagebe ti iṣe ẹlẹya li apejẹ, nwọn npa ehin wọn si mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn àgàbàgebè ń ṣe yẹ̀yẹ́ mi ṣíwájú àti sí wájú síi wọ́n pa eyín wọn keke sí mi.