Psalms 35:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, yóo ti pẹ́ tó, tí o óo máa wò mí níran? Yọ mí kúrò ninu ogun tí wọn gbé tì mí, gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn kinniun!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa iwọ o ti ma wò pẹ to? yọ ọkàn mi kuro ninu iparun wọn, ẹni mi kanna lọwọ awọn kiniun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò ti pẹ́tó, ìwọ OLÚWA, tí ìwọ yóò máa wò wọ́n lọ? Yọ mí kúrò nínú ìparun wọn àní ẹ̀mí i mi kúrò lọ́wọ́ kìnnìún.