Psalms 35:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni n óo máa sọ̀rọ̀ òdodo rẹ, n óo sì máa yìn ọ́ tọ̀sán-tòru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ahọn mi yio si ma sọ̀rọ ododo rẹ, ati ti iyìn rẹ ni gbogbo ọjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ahọ́n mi yóò máa sọ̀rọ̀ òdodo Rẹ, àti ìyìn Rẹ ní gbogbo ọjọ́.