Psalms 35:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí wọ́n dẹ àwọ̀n sílẹ̀ fún mi láìnídìí, wọ́n sì gbẹ́ kòtò sílẹ̀ dè mí láìnídìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe, li ainidi ni nwọn dẹ àwọn wọn silẹ fun mi, nwọn wà iho silẹ fun ọkàn mi li ainidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé, ní àìnídìí ní wọ́n dẹ àwọ̀n wọn sílẹ̀ fún mi, ní àìnídìí ni wọ́n wa kòtò fún ọkàn mi.