Psalms 36:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé lọ́dọ̀ rẹ ni orísun ìyè wà; ninu ìmọ́lẹ̀ rẹ ni a ti ń rí ìmọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe pẹlu rẹ li orisun ìye wà: ninu imọlẹ rẹ li awa o ma ri imọlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé pẹ̀lú ù Rẹ ni orísun ìyè wà: nínú ìmọ́lẹ̀ Rẹ ni àwa yóò rí ìmọ́lẹ̀.