Psalms 37:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ fún eniyan burúkú ní ìgbà díẹ̀ sí i, yóo pòórá; ẹ̀ báà wá a títí ní ààyè rẹ̀, kò ní sí níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe nigba diẹ, awọn enia buburu kì yio si: nitotọ iwọ o fi ara balẹ wò ipò rẹ̀, kì yio si si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀ nígbà díẹ̀ síi,, àwọn ènìyàn búburú kì yóò sí mọ́ nítòótọ́ ìwọ yóò fi ara balẹ̀ wo ipò Rẹ̀, wọn kì yóò sí níbẹ̀.