Psalms 37:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí eniyan burúkú bá yá owó, kò ní san; ṣugbọn ẹni rere ní ojú àánú, ó sì lawọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia buburu wín, nwọn kò si pada san: ṣugbọn olododo a ma ṣãnu, a si ma fi funni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn búburú yá, wọn kò sì san-án padà, ṣùgbọ́n àwọn olódodo a máa fi fún ni;