Psalms 37:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Olódodo ní ojú àánú, a sì máa yáni ní nǹkan, ayọ̀ ń bẹ fún àwọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alãnu li on nigbagbogbo, a ma wín ni: a si ma busi i fun iru-ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Aláàánú ni òun nígbà gbogbo a máa yá ni; a sì máa bùsí i fún ni.