Psalms 37:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, sì máa tọ ọ̀nà rẹ̀, yóo gbé ọ ga, kí o lè jogún ilẹ̀ náà; nígbà tí a bá pa àwọn eniyan burúkú run, o óo fojú rẹ rí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Duro de Oluwa, ki o si ma pa ọ̀na rẹ̀ mọ́, yio si gbé ọ leke lati jogun aiye: nigbati a ba ké awọn enia buburu kuro, iwọ o ri i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dúró de OLÚWA, kí o sì má a pa ọ̀nà Rẹ̀ mọ́, yóò sì gbé ọ lékè láti jogún ilẹ̀ náà: Nígbà tí a bá gé àwọn ènìyàn búburú kúrò ìwọ yóò ri.