Psalms 37:38 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yóo parun patapata, a óo sì run ọmọ àwọn eniyan burúkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn alarekọja li a o parun pọ̀; iran awọn enia buburu li a o ké kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àwọn olùrékọjá ní a ó parun papọ̀; ìran àwọn ènìyàn búburú ní a ó gé kúrò.