Psalms 37:39 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀dọ̀ OLUWA ni ìgbàlà àwọn olódodo ti ń wá; òun ni alátìlẹ́yìn wọn ní àkókò ìṣòro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn lati ọwọ Oluwa wá ni igbala awọn olododo; on li àbo wọn ni igba ipọnju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbàlà àwọn adúró ṣinṣin wa láti ọ̀dọ̀ OLÚWA: òun ni ààbò wọn ní ìgbà ìpọ́njú