Psalms 37:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yẹra fún ibinu; sì yàgò fún ìrúnú. Má gbé ara rẹ lọ́kàn gbóná; ibi ni àyọrísí rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dakẹ inu-bibi, ki o si kọ̀ ikannu silẹ: máṣe ikanra, ki o má ba ṣe buburu pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fàsẹ́yìn nínú inúbíbí, kí o sì kọ ìkannú sílẹ̀. Má ṣe ṣe ìkanra, nítorí pé ó gbéni sí búburú pẹ̀lú.