Psalms 37:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé a óo pa àwọn eniyan burúkú run; ṣugbọn àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA ni yóo jogún ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti a o ke awọn oluṣe-buburu kuro: ṣugbọn awọn ti o duro de Oluwa ni yio jogun aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé á ó gé àwọn ènìyàn búburú kúrò, Ṣùgbọ́n àwọn tí ó bá dúró de OLÚWA àwọn ni yóò jogún ilẹ̀ náà.