Psalms 38:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí mi dẹ tàkúté sílẹ̀ dè mí, àwọn tí ń wá ìpalára mi ń sọ̀rọ̀ ìparun mi, wọ́n sì ń pète àrékérekè tọ̀sán-tòru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn pẹlu ti nwá ọkàn mi dẹkùn silẹ fun mi; ati awọn ti nwá ifarapa mi nsọ̀rọ ohun buburu, nwọn si ngbiro ẹ̀tan li gbogbo ọjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí n wá ẹ̀mí mi dẹ okùn sílẹ̀ fún mi; àti àwọn tí ó fẹ́ pa mí lára ń sọ̀rọ̀ nípa ìparun, wọ́n sì ń gbérò ẹ̀tàn ní gbogbo ọjọ́.