Psalms 38:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí tí mò ń gbadura pé, kí àwọn tí ń pẹ̀gàn mi má yọ̀ mí nígbà tí ẹsẹ̀ mi bá yẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti mo wipe, Gbohùn mi, ki nwọn ki o má ba yọ̀ mi; nigbati ẹsẹ mi ba yọ́, nwọn o ma gbé ara wọn ga si mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí mo gbàdúrà, “Gbóhùn mi, kí wọn má ba à yọ̀ mí; nígbà tí ẹsẹ̀ mi bá yọ̀ wọn yóò máa gbé ara wọn ga sí mi”.