Psalms 38:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí ń bá mi ṣọ̀tá láìnídìí lágbára, àwọn tí ó kórìíra mi láìtọ́ sì pọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ara yá awọn ọta mi, ara wọn le; awọn ti o korira mi lodi npọ̀ si i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láì ní ìdí pàtàkì, wọ́n lágbára púpọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí ó kórìírá mi lọ́nà òdì.