Psalms 38:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí ń fi ibi san oore fún mi ní ń gbógun tì mí, nítorí pé rere ni mò ń ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o si nfi buburu san rere li ọta mi; nitori emi ntọpa ohun ti iṣe rere.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí wọn ń fi ibi san rere fún mi àwọn ni ọ̀ta mi nítorí pé mò ń tọ ire lẹ́yìn.