Psalms 38:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò sí ibìkan tí ó gbádùn ní gbogbo ara mi nítorí ibinu rẹ; kò sì sí alaafia ninu gbogbo egungun mi, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kò si ibi yíyè li ara mi nitori ibinu rẹ; bẹ̃ni kò si alafia li egungun mi nitori ẹ̀ṣẹ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò sí ibi yíyè ní ara à mi nítorí ìbínú Rẹ; kò sí àlàáfíà nínú egungun mi nítorí i ẹ̀ṣẹ̀ mi.