Psalms 39:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ìdààmú dé bá ọkàn mi. Bí mo ti ń ronú, ọkàn mi dàrú; mo bá sọ̀rọ̀ jáde, mo ní:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aiya mi gbona ninu mi, nigbati emi nronu, ina ràn: nigbana ni mo fi ahọn mi sọ̀rọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àyà mi gbóná ní inú mi, nígbà tí mo ń ṣàṣàrò, ina ràn; nígbà náà ni mo fi ahọ́n mi sọ̀rọ̀.